Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 18:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n àwọn ọmọ Léfì kò ní ìpín ní àárin yín, nítorí iṣẹ́ àlùfáà. Olúwa ni ìní wọ́n. Gádì, Rúbẹ́nì àti ìdajì ẹ̀yà Mánásè, ti gba ìní wọn ní ìhà ìlà-oòrùn Jọ́dánì. Mósè ìránṣẹ́ Olúwa ti fi fún wọn.”

Ka pipe ipin Jóṣúà 18

Wo Jóṣúà 18:7 ni o tọ