Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 18:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìhà àríwá ààlà wọn bẹ̀rẹ̀ ní Jọ́dánì, ó kọjá lọ sí gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ Jẹ́ríkò ní ìhà àríwá, ó sì forílé ìwọ̀-oòrùn sí ìlú òkè, jáde sí asálẹ̀ Bẹti-Áfẹ́nì.

Ka pipe ipin Jóṣúà 18

Wo Jóṣúà 18:12 ni o tọ