Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 17:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Agbégbé Mánásè sì fẹ̀ láti Áṣírìu títí dé Míkímẹ́tatì ní ìlà oòrùn Sékémù. Ààlà rẹ̀ sì lọ sí ìhà gúsù títí tó fi dé ibi tí àwọn ènìyàn ń gbé ní Tápúà,

Ka pipe ipin Jóṣúà 17

Wo Jóṣúà 17:7 ni o tọ