Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 17:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà ìpín yìí wà fún ìyókù àwọn ènìyàn Mánásè: ní agbo ilé Ábíésérì, Hélékì, Ásíríélì, Sékémù, Héférì àti Ṣémídà. Ìwọ̀nyí ní àwọn ọmọ ọkùnrin Mánásè ọmọ Jósẹ́fù ní agbo ilé wọn.

Ka pipe ipin Jóṣúà 17

Wo Jóṣúà 17:2 ni o tọ