Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 17:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Jóṣúà sọ fún àwọn ilé Jósẹ́fù: fún Éfúráímù àti Mánásè pé, “Lóòtọ́ ni ẹ pọ̀ lọ́pọ̀lọpọ̀, ẹ sì jẹ́ alágbára. Ẹ̀yin kí yóò sì ní ìpín kan ṣoṣo.

Ka pipe ipin Jóṣúà 17

Wo Jóṣúà 17:17 ni o tọ