Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 17:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àárin Ísákárì àti Ásérì, Mánásè tún ni Bẹti-Ṣánì, Íbílémù àti àwọn ènìyàn Dórì, Énídórì, Táánákì àti Mégídò pẹ̀lú àwọn abúlé tí ó yí wọn ká (ìkẹ́ta nínú orúkọ wọn ní Náfótì).

Ka pipe ipin Jóṣúà 17

Wo Jóṣúà 17:11 ni o tọ