Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 16:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìpín ti Jósẹ́fù bẹ̀rẹ̀ láti odò Jọ́dánì ní Jẹ́ríkò, ó sì la aṣálẹ̀ kọjá láti ibẹ̀ sí ọ̀nà ihà sí òkè ìlú Bẹ́tẹ́lì.

Ka pipe ipin Jóṣúà 16

Wo Jóṣúà 16:1 ni o tọ