Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 14:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí Olúwa ti ṣe ìlérí, o ti mú mi wà láàyè fún ọdún márùn-úndínláàádọ́ta láti ìgbà tí ó ti sọ fún Mósè. Nígbà tí Ísírẹ́lì ń rìn kiri nínú aṣálẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni èmi náà sì nìyí lónìí, ọmọ ọgọ́rin ọdún ó lé márùn-ún.

Ka pipe ipin Jóṣúà 14

Wo Jóṣúà 14:10 ni o tọ