Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 13:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ní ti gbogbo àwọn olùgbé agbégbé òkè, láti Lẹ́bánónì sí Mísiréífótì-Máímù, àní, gbogbo àwọn ará Sídónì, èmi fúnra mi ní yóò lé wọn jáde ní iwájú àwọn ará Ísírẹ́lì. Kí o ri dájú pé o pín ilẹ̀ yí fún Ísírẹ́lì ní ilẹ̀ ìní, gẹ́gẹ́ bí mo ṣe fi àṣẹ fún ọ,

Ka pipe ipin Jóṣúà 13

Wo Jóṣúà 13:6 ni o tọ