Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 13:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

àti ní àfonífojì Bẹti-Hárámù, Bẹti-Nímírà, Súkótìọ àti Sáfónì pẹ̀lú ìyókù agbégbé ilẹ̀ Síhónì ọba Héṣíbónì (ní ìhà ìlà oòrùn Jọ́dánì, agbégbé rẹ̀ títí dé òpin Òkun Kínẹ́rítì).

Ka pipe ipin Jóṣúà 13

Wo Jóṣúà 13:27 ni o tọ