Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 13:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

gbogbo ìlú tí ó wà ní pẹ̀tẹ́lẹ̀e àti gbogbo agbégbé Síhónì ọba Ámórì, tí ó ṣe àkóso Héṣíbónì. Mósè sì ti sẹ́gun rẹ̀ àti àwọn ọmọ ìjòyè Mídíánì, Éfì, Rékémì, Súrì, Húrì àti Rébà, àwọn ọmọ ọba pàmọ̀pọ̀ pẹ̀lú Síhónì tí ó gbé ilẹ̀ náà.

Ka pipe ipin Jóṣúà 13

Wo Jóṣúà 13:21 ni o tọ