Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 13:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n àwọn ará Ísírẹ́lì kò lé àwọn ará Géṣúrì àti Máákà jáde, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ń gbé ní àárin àwọn ará Ísírẹ́lì títí di òní yìí.

Ka pipe ipin Jóṣúà 13

Wo Jóṣúà 13:13 ni o tọ