Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 11:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ní Jóṣúà sì gba gbogbo ilẹ̀ náà, gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ fún Mósè, ó sì fi fún Ísírẹ́lì ní ilẹ̀-ìní gẹ́gẹ́ bí ìpín wọn nípa ẹ̀yà wọn.Ilẹ̀ náà sì sinmi ogun.

Ka pipe ipin Jóṣúà 11

Wo Jóṣúà 11:23 ni o tọ