Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 11:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àkókò náà ni Jóṣúà lọ tí ó sì run àwọn ará Ánákì kúrò ní ilẹ̀ òkè, láti Hébúrónì, Débírì, àti ní Ánábù, àti gbogbo ilẹ̀ Júdà, àti kúrò ní gbogbo ilẹ̀ òkè Ísírẹ́lì. Jóṣúà sì run gbogbo wọn pátapáta àti ìlú wọn.

Ka pipe ipin Jóṣúà 11

Wo Jóṣúà 11:21 ni o tọ