Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 11:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

láti òkè Hálakì títí dé òkè Séírì, sí Báálì-Gádì ní Àfonífojì Lẹ́bánónì ní ìsàlẹ̀ òkè Hámónì. Ó sì mú gbogbo ọba wọn, ó sì kọlù wọ́n, ó sì pa wọ́n.

Ka pipe ipin Jóṣúà 11

Wo Jóṣúà 11:17 ni o tọ