Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 11:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ará Ísírẹ́lì sì kó gbogbo ìkógún àti ohun ọ̀sìn ti ìlú náà fún ara wọn. Wọ́n sì fi idà pa gbogbo ènìyàn títí wọ́n fi run wọ́n pátapáta, kò sí ẹni tí ó wà láàyè.

Ka pipe ipin Jóṣúà 11

Wo Jóṣúà 11:14 ni o tọ