Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 1:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ la ibùdó já, kí ẹ sì sọ fún àwọn ènìyàn, Ẹ pèṣè oúnjẹ yín sílẹ̀. Ní ìwòyí ọ̀túnla, ẹ̀yin yóò la Jọ́dánì yìí kọjá, láti gba ilẹ̀ tí Olúwa Ọlọ́run yín fi fún un yín láti ní.”

Ka pipe ipin Jóṣúà 1

Wo Jóṣúà 1:11 ni o tọ