Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 8:7-11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

7. Ìpilẹsẹ̀ rẹ ìbá tilẹ̀ kéré si í,bẹ́ẹ̀ ìgbẹ̀yin rẹ ìbá pọ̀ sí i gidigidi.

8. “Èmi bẹ̀ ọ́ ǹjẹ́, bèèrè lọ́wọ́ àwọn ará ìgbà nìkí o sì kíyèsí ìwádìí àwọn baba wọn.

9. Nítorí pé ọmọ-àná ni àwa, a kò sì mọ nǹkan,nítorí pé òjìji ni ọjọ́ wa ni ayé.

10. Àwọn kì yóò wa kọ ọ́, wọn kì yóò sì sọ fún ọ?Wọn kì yóò sì sọ̀rọ̀ láti inú òye wọn jáde wá?

11. Koríko odò ha lè dàgbà láìní ẹrẹ̀tàbí èèsú ha lè dàgbà láìlómi?

Ka pipe ipin Jóòbù 8