Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 8:18-22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

18. Bí ó bá sì pa á run kúrò ní ipò rẹ̀,nígbà náà ni ipò náà sẹ́ ẹ pé, ‘Èmi kò ri ọ rí!’

19. Kíyèsí i, ayé rẹ̀ gbẹ dànùàti lati inú ilẹ̀ ní irúgbìn òmìíràn yóò hù jáde wá.

20. “Kíyèsí i, Ọlọ́run kì yóò ta ẹni òtítọ́ nù,bẹ́ẹ̀ ni kì yóò ran oníwà-búburú lọ́wọ́

21. títí yóò fi fi ẹ̀rín kún ọ ní ẹnu,àti ètè rẹ pẹ̀lú ìhó ayọ̀

22. ìtìjú ní a o fi bo àwọn tí ó koríra rẹ̀,àti ibùjókòó ènìyàn búburú kì yóò sí mọ́.”

Ka pipe ipin Jóòbù 8