Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 7:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èéṣe tí ìwọ kò sì dárí ìrékọjá mi jìn,kí ìwọ kí ó sì mú aìṣédéédéé mi kúrò?Ǹjẹ́ nísinsìn yìí ni èmi ìbá sùn nínú erùpẹ̀,ìwọ ìbá sì wá mi kiri ní owúrọ̀, èmi kì bá tí sí.”

Ka pipe ipin Jóòbù 7

Wo Jóòbù 7:21 ni o tọ