Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 6:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Jóòbù sì dáhùn ó si wí pé:

2. “Áà! à bá lè wọ̀n ìbìnújẹ́ mi nínú òṣùwọ̀n,kí a sì le gbé ọ̀fọ̀ mi lé orí òṣùwọ̀n ṣọ̀kan pọ̀!

3. Ǹjẹ́ nísinsìn yìí, ìbá wúwo jú iyánrìn òkun lọ:nítorí náà ni ọ̀rọ̀ mi ṣe ń tàsé

4. Nítorí pé ọfà Olódùmárè wọ̀ mi nínú,oró èyí tí ọkàn mi mú;ìpayà-ẹ̀rù Ọlọ́run dúró tì mí.

Ka pipe ipin Jóòbù 6