Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 41:31-33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

31. Ó mú ibú omi hó bí ìkòkò; ó sọ̀agbami òkun dàbí kólòbó ìkunra.

32. Ó mú ipa ọ̀nà tan lẹ́yìn rẹ̀; ènìyàna máa ka ibú sí ewú arúgbó.

33. Lórí ilẹ̀ ayé kò sí ẹni tí ó dàbí rẹ̀,tí a dá láìní ìbẹ̀rù.

Ka pipe ipin Jóòbù 41