Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 40:7-11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

7. “Di àmùrè gíri ní ẹgbẹ́ rẹ, èmi ó biọ léèrè, kí ìwọ kí ó sì dá mi lóhùn.

8. “Ìwọ ha fẹ́ mú ìdájọ́ mi di asán?Ìwọ ó sì dá mi lẹ́bi, kí ìwọ lè ṣe olódodo

9. Ìwọ ni apá bí Ọlọ́run tàbí ìwọ lèfi ohùn sán àrá bí òun?

10. Fi ọlá ńlá àti ọlá ìtayọ rẹ̀ ṣe ararẹ ní ọ̀ṣọ́, tí ó sì fi ògo àti títóbi ọ̀ṣọ́ bi ara ní aṣọ.

11. Mú ìrúnu ìbínú rẹ jáde; kíyèsígbogbo ìwà ìgbéraga rẹ kí o sì rẹ̀ ẹ́ sílẹ̀

Ka pipe ipin Jóòbù 40