Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 33:31-33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

31. “Jóòbù, kíyèsìí gidigidi kí o sì fetísí mi; pa ẹnu rẹ mọ́, èmi ó sì máa sọ ọ́

32. Bí ìwọ bá sì ní ohun íwí, dámi lóhùn; máa sọ, nítorí pé èmi fẹ́ dá ọ láre.

33. Bí bẹ́ẹ̀ kọ́, gbọ́ tèmi; pa ẹnu rẹmọ́ èmi ó sì kọ́ ọ ní ọgbọ́n.”

Ka pipe ipin Jóòbù 33