Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 33:16-20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

16. Nígbà náà ni ó lè sọ̀rọ̀ ní etíwọn, yóò sì dẹ́rùbà wọ́n pẹ̀lú ìbáwí,

17. Kí ó lè fa ènìyàn sẹ́yìn kúrò nínúètè rẹ̀; Kí ó sì pa ìgbéraga mọ́ kúrò lọ́dọ̀ ènìyàn;

18. Ó sì fa ọkàn rẹ̀ pàdà kúro nínúìsà-òkú, àti ẹ̀mí rẹ̀ láti ṣẹ̀gbé lọ́wọ́ ìdà.

19. A sì nà á lórí ibùsùn ìrọra rẹ̀;Pẹ̀lúpẹ̀lú a fi ìjà egungun rẹ̀ ti ó dúró pẹ́ nà án.

20. Bẹ́ẹ̀ ni ẹ̀mírẹ kọ ounjẹ, ọkàn rẹ̀ sì kọ oúnjẹ dídùn.

Ka pipe ipin Jóòbù 33