Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 33:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. “Njẹ́ nítorí náà, Jóòbù, èmí bẹ̀ọ, gbọ́ ọ̀rọ̀ mi kí o sì fetísí ọ̀rọ̀ mi!

2. Kíyèsí i nísinsìnyí, èmí ya ẹnumi, ahọ́n mi sì sọ̀rọ̀ ní ẹnu mi.

3. Ọ̀rọ̀ mi yóò sì jási ìdúró ṣinṣinọkàn mi, ètè mi yóò sì sọ ìmọ̀ mi jáde dájúdájú.

Ka pipe ipin Jóòbù 33