Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 32:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Inú sì bí i sí àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta, nítorí tí wọn kò rí ọ̀nà láti dá Jóòbù lóhùn bẹ́ẹ̀ ni wọ́n dá Jóòbù lẹ́bi.

Ka pipe ipin Jóòbù 32

Wo Jóòbù 32:3 ni o tọ