Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 31:1-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. “Mo ti bá ojú mi dá májẹ̀mu,èmi yó ha ṣe tẹjú mọ́ wúndíá?

2. Nítórí pé kí ni ìpín Ọlọ́run láti ọ̀run wá?Tàbí kí ni ogún Olódùmárè láti òkè ọ̀run wá.

3. Kò ṣe pé àwọn ènìyàn búburú niìparun wà fún, àti àjàkálẹ̀àrùn fún àwọn oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀?

4. Òun kò ha ri ipa ọ̀nà mi, òun kòha sì ka gbogbo ìṣíṣẹ̀ mi?

5. “Bí ó bá ṣepé èmi bá fi àìṣòótọ́ rìn,tàbí tí ẹsẹ̀ mi sì yára sí ẹ̀tàn;

Ka pipe ipin Jóòbù 31