Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 30:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. “Ṣùgbọ́n nísinsin yìí,àwọn tí mo gbà ní àbúrò ń fi míṣe ẹlẹ́yà, baba ẹni tí èmi kẹ́gànláti tò pẹ̀lú àwọn ajá agbo-ẹran mi.

2. Kí ni ìwúlò agbára ọwọ́ wọn sími,níwọ̀n ìgbà tí agbára wọn ti fi wọ́n sílẹ̀?

3. Wọ́n rù nítorí àìní àti ìyànwọ́n ń rìn káàkiri ní ilẹ̀ gbígbẹní ibi ìkọsílẹ̀ ní òru.

Ka pipe ipin Jóòbù 30