Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 3:13-16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

13. Ǹjẹ́ nísinsìn yìí èmi ìbá ti dúbúlẹ̀ jẹ́ẹ́;èmi a sì dákẹ́, èmi ìbá ti sùn ǹjẹ́ èmi ìbá ti sinmi

14. pẹ̀lú àwọn ọba àti ìgbìmọ̀ ayétí ìmọ́lẹ̀ takété fún ara wọn.

15. Tàbí pẹ̀lú àwọn ọmọ-aládétí ó ní wúrà, tí wọ́n sì fi fàdákà kun ilé wọn

16. Tàbí bí ọ̀lẹ̀ tí a sin, èmi kì bá ti sí:bí ọmọ ìṣúnú tí kò rí ìmọ́lẹ̀?

Ka pipe ipin Jóòbù 3