Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 3:11-14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

11. “Èéṣe tí èmi kò fi kú láti inú wá,tàbí tí èmi kò fi pín ẹ̀mí ní ìgbà tí mo ti inú jáde wá?

12. Èéṣe tí eékún wá pàdé mi,tàbí ọmú tí èmi yóò mu?

13. Ǹjẹ́ nísinsìn yìí èmi ìbá ti dúbúlẹ̀ jẹ́ẹ́;èmi a sì dákẹ́, èmi ìbá ti sùn ǹjẹ́ èmi ìbá ti sinmi

14. pẹ̀lú àwọn ọba àti ìgbìmọ̀ ayétí ìmọ́lẹ̀ takété fún ara wọn.

Ka pipe ipin Jóòbù 3