Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 25:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ígbà náà ní Bílídádì, ará Ṣúà, dáhùn wí pé:

2. “Ìjọba àti ẹ̀ru ḿbẹ lọ́dọ̀ Ọlọ́run rẹ̀,òun ní iṣe ìlàjà ní ibi gígagíga ọ̀run.

3. Àwọn ọmọ-ogun rẹ̀ ha ní ìyè bí,tàbí ara tani ìmọ́lẹ̀ rẹ̀ kò tàn sí?

4. Èé ha ti ṣe tí a ó fi dá ènìyàn láre lọ́dọ̀ Ọlọ́run?Tàbí ẹni tí a bí láti inú obìnrin wá yóò ha ṣe mọ́?

Ka pipe ipin Jóòbù 25