Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 24:23-25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

23. Ọlọ́run sì fi ìwà àìléwu fún un,àti nínú èyí ní a ó sì tì i lẹ́yìn, ojúrẹ̀ sì wà ní ipa ọ̀nà wọn.

24. A gbé wọn lékè nígbà díẹ̀; wọ́nkọjá lọ, a sì rẹ̀ wọ́n sílẹ̀; A sìmú wọn kúrò ní ọ̀nà, bí àwọnẹlòmìíràn, a sì ké wọn kúrò bí orí sírì itú ọkà bàbà.

25. “Ǹjẹ́, bí kò bá rí bẹ́ẹ̀ nísinsìn yìí,ta ni yóò mú mi ní èké,tí yóò sì sọ ọ̀rọ̀ mi di aláìníláárí?”

Ka pipe ipin Jóòbù 24