Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 20:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ígbà náà ní Sófárì, ara Náámà dáhùn, ó sì wí pé:

2. “Nítorí náà ní ìro inú mi dá mi lóhùn,àti nítorí èyí náà ní mo sì yára si gidigidi.

3. Mo ti gbọ́ ẹ̀san ẹ̀gàn mi, ẹ̀mí òyemi sì dá mi lóhùn.

Ka pipe ipin Jóòbù 20