Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 19:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ígbà náà ni Jóòbù dáhùn, ó sì wí pé:

2. “Yóò ti pẹ́ tó tí ẹ̀yin ó fi máa fi ìyàjẹ mí, tí ẹ̀yin ó fi máa fi ọ̀rọ̀ mi ní ìjàǹjá?

3. Ìgbà mẹ́wàá ní ẹ̀yin ti ń gàn mí;ojú kò tìyín tí ẹ fi jẹ mí níyà.

Ka pipe ipin Jóòbù 19