Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 17:13-16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

13. Bí mo tilẹ̀ ní ìrètí, ipò òku ní ilémi; mo ti tẹ́ ìbùsùn mi sínú òkùnkùn.

14. Èmi ti wí fún ìdibàjẹ́ pé, ìwọ nibaba mi, àti fún kòkòrò pé,ìwọ ni ìyá mi àti arábìnrin mi,

15. Ìrètí mi ha dà nísinsinyí? Bí ó ṣeti ìrètí mi ni, ta ni yóò rí i?

16. Yóò sọ̀kalẹ̀ lọ sínú ipò òkú,nígbà tí a jùmọ̀ sinmi pọ̀ nínú erùpẹ̀ ilẹ̀?”

Ka pipe ipin Jóòbù 17