Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 16:5-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

5. Èmi ìbá fi ọ̀rọ̀ ẹnu mi gbà yín niìyànjú, àti ṣíṣí ètè mi ìbá sì tu ìbìnújẹ́ yín.

6. “Bí èmi tilẹ̀ sọ̀rọ̀, ìbìnújẹ́ mi kò tù;bí mo sì tilẹ̀ dákẹ́, níbo ni ìtùnú mí dé?

7. Ṣùgbọ́n nísinsin yìí, ó dá milágara; Ìwọ (Ọlọ́run) mú gbogbo ẹgbẹ́ mi takété.

Ka pipe ipin Jóòbù 16