Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 16:21-22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

21. Ìbáṣe pé ẹnìkan le è máa ṣe alágbàwífún ẹnìkejì lọ́dọ̀ Ọlọ́run,bí ènìyàn kan ti íṣe alágbàwí fún ẹnìkejì rẹ̀.

22. “Nítorí nígbà tí iye ọdun díẹ̀ rékọjátán, nígbà náà ni èmi ó lọ sí ibi tí èmi kì yóò padà bọ̀.

Ka pipe ipin Jóòbù 16