Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 16:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ígbà náà ní Jóòbù dáhùn, ó sì wí pé:

2. “Èmi ti gbọ́ irú ohun pípọ̀ bẹ́ẹ̀ ríayọnilẹ́nu onítùnú ènìyàn ní gbogbo yín.

3. Ọ̀rọ̀ asán lè ni òpin? Tàbí nín ni ógbó ọ láyà tí ìwọ fi dáhùn?

Ka pipe ipin Jóòbù 16