Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 15:5-9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

5. Nítorí pé ẹnu ara rẹ̀ ni ó jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀rẹ̀, ìwọ sì yàn ahọ́n alárékérekè ni ààyò.

6. Ẹnu ara rẹ̀ ni ó dá lẹ́bi, kì í ṣe èmi;àní ètè ara rẹ̀ ni ó jẹ́rìí tì ọ́.

7. “Ìwọ ha íse ọkùnrin tí a kọ́ bi? Tabìa há dá ọ ṣáájú àwọn òkè?

8. Ìwọ gburòó àsírí Ọlọ́run rí, tàbíìwọ ha dá ọgbọ́n dúró sọ́dọ̀ ara rẹ?

9. Kí ni ìwọ mọ̀ tí àwa kò mọ̀? Òyekí ní ó yé ọ tí kò sí nínú wa?

Ka pipe ipin Jóòbù 15