Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 13:5-9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

5. Áà! ẹ̀yin kì bá kúkú dákẹ́! Èyi nikì bá sì ṣe ọgbọ́n yín.

6. Ẹ gbọ́ àwíyé mi nísinsìn yìí, Ẹ sìfetísilẹ̀ sí àròyé ètè mi.

7. Èyin fẹ́ sọ ìsọkúsọ fún Ọlọ́run? Kiẹ sì fi ẹ̀tàn sọ̀rọ̀ gbè é?

8. Ẹ̀yin fẹ́ ṣojúṣaajú rẹ̀? Ẹ̀yin fẹ́gbèjà fún Ọlọ́run?

9. Ó ha dára tí yóò fi húdìí yín sílẹ̀,Tàbí kí ẹ̀yin tàn án bí ẹnìkan ti ítan ẹnìkejì?

Ka pipe ipin Jóòbù 13