Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 13:1-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. “Ò ó, ojú mi ti rí gbogbo èyí rí,Etí mí sì gbọ́, ó sì ti yé e.

2. Ohun tí ẹ̀yin mọ̀, èmi mọ̀ pẹ̀lú,èmi kò rẹ̀yìn sí yin.

3. Nítòótọ́ èmi ó bá Olódumárèsọ̀rọ̀, Èmi sì ń fẹ́ bá Ọlọ́run sọ àsọyé.

4. Èyin ni oníhùmọ̀ èké, oníṣègùnlásán ni gbogbo yín

5. Áà! ẹ̀yin kì bá kúkú dákẹ́! Èyi nikì bá sì ṣe ọgbọ́n yín.

Ka pipe ipin Jóòbù 13