Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 11:9-13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

9. Ìwọ̀n rẹ̀ gùn ju ayé lọ,ó sì ní ibú ju òkun lọ.

10. “Bí òun bá rékọjá, tí ó sì sénà,tàbí tí ó sì mú ni wá sí ìdajọ́, ǹjẹ́, ta ni ó lè dí i lọ́wọ́?

11. Òun sáà mọ ènìyàn asán;àti pé ṣé bí òun bá rí ohunbúburú, ṣé òun kì i fi iyè sí i?

12. Ṣùgbọ́n òmùgọ̀ ènìyàn yóò di ọlọgbọ́n,nígbà tí ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ bá bí ènìyàn.

13. “Bí ìwọ bá fi ọkàn rẹ fún un,tí ìwọ sì na ọwọ́ rẹ sí ọ̀dọ̀ rẹ̀,

Ka pipe ipin Jóòbù 11