Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 11:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí pé ìwọ ó gbàgbé ìṣòro rẹ,ìwọ ó sì rántí rẹ̀ bí omi tí ó ti ṣàn kọjá lọ.

Ka pipe ipin Jóòbù 11

Wo Jóòbù 11:16 ni o tọ