Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóòbù 10:20-22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

20. Ọjọ́ mi kò ha kúrú bí? Rárádáwọ́ dúró, kí ó sì yí padà kúrò lọ́dọ̀ minítorí kí èmi lè ni ayọ̀ ní ìṣẹ́jú kan

21. Kí èmi kí ó tó lọ síbi tí èmi kì yóò padà sẹ́yìn mọ́,Àní kí ilẹ̀ òkùnkùn àti òjìji ikú,

22. Ilẹ̀ òkùnkùn bí òkùnkùn tìkárarẹ̀,Àti ti òjìji ikú, láìní ìtọ́,Níbi tí ìmọ́lẹ̀ dàbí òkùnkùn.”

Ka pipe ipin Jóòbù 10