Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jónà 2:9-10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

9. Ṣùgbọ́n èmi yóò fi orin ọpẹ́, rúbọ sí ọ.Èmi yóò san ẹ̀jẹ́ tí mo ti jẹ́.‘Igbàlà wá láti ọdọ Olúwa.’ ”

10. Olúwa sì pàṣẹ fún ẹja náà, ó sì pọ Jónà sí orí ilẹ̀ gbígbẹ.

Ka pipe ipin Jónà 2