Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jónà 2:6-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

6. Èmi ṣọ̀kalẹ̀ lọ sí ìṣàlẹ̀ àwọn òkè ńlá;ilẹ̀ ayé pẹ̀lú ìdènà rẹ̀ yí mi ká títí:ṣùgbọ́n ìwọ ti mú ẹ̀mí mi wá sókè láti inú ibú wá, Olúwa Ọlọ́run mi.

7. “Nígbà tí ó rẹ ọkàn mi nínú mi,èmi rántí rẹ, Olúwa,àdúrà mi sì wá sí ọ̀dọ̀ rẹ,nínú tẹ́ḿpìlì mímọ́ rẹ.

8. “Àwọn tí ń fàmọ́ òrìṣà èkékọ àánú ara wọn sílẹ̀.

Ka pipe ipin Jónà 2