Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jónà 1:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun sì dá wọn lóhùn pé, “Hébérù ni èmi, mo sì bẹ̀rù Olúwa, Ọlọ́run ọ̀run ẹni tí ó dá òkun àti ìyàngbẹ ilẹ̀.”

Ka pipe ipin Jónà 1

Wo Jónà 1:9 ni o tọ