Nígbà náà ni wọ́n wí fún un pé, “Kí ni kí àwa ó se sí ọ kí òkun lè dákẹ́ fún wa?” Nítorí òkun ru, ó sì ja ẹ̀fúùfù líle.