Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóẹ́lì 3:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa yóò sí ké ramúramú láti Ṣíónì wá,yóò sì fọ ohùn rẹ̀ jáde láti Jérúsálẹ́mù wá;àwọn ọ̀run àti ayé yóò sì mì tìtìṢùgbọ́n Olúwa yóò ṣe ààbò àwọn ènìyàn rẹ̀,àti agbára àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Jóẹ́lì 3

Wo Jóẹ́lì 3:16 ni o tọ